Songtext
Wähl bis zu sechs Zeilen für eine Karte aus.
Wọ́n fẹ́ mi níyẹn, níyẹn
Wọ́n fẹ́ mi níyẹn, níyẹn
Èmi náà kọ́, Ọlọ́run Ọba mi
Wọ́n fẹ́ mi níyẹn, níyẹn
(Tune in—)
Àwa dé, dé, dé, dé, dé, dé, àwa dé
Àwa la ń gbé wọn dé'bẹ̀, àwa dé o, mm
Àwa dé, dé, dé, dé, dé, dé, àwa dé
Ṣebí àwa la ń gbé wọn dé'bẹ̀? (Boss)
Torí kí n lè make ẹ̀, mo ṣe sá nílé
Ah, mo mọ̀ pé ó ń gb'óhùn mi from miles away
Ah, Yahweh, Yahweh, jọ̀wọ́ bá mi ṣe (Ooh)
To avoid the banter, mo ń calculate
Ah, mi ò mọ̀ pé ojú ogun le, ń bá ti gbé bazooka
I saw some shege, àánú ṣáà ni mo ń rí gbà
So, Ẹlẹ́dàá mi, mo bẹ̀bẹ̀
Ibi t'ọ́n wa moto, kí n má lọ lo keke
I for don die, ọpẹ́lọpẹ́ mo rí jà
Àwa dé, dé, dé, dé, dé, dé, àwa dé
Àwa la ń gbé wọn dé'bẹ̀, àwa dé o, mm
Àwa dé, dé, dé, dé, dé, dé, àwa dé
Ṣebí àwa la ń gbé wọn dé'bẹ̀?
I don't know, oh, I don't know
Ọmọ ń gb'àdúrà
K'ọ́n ma kó mi jẹ bí Yàkọ́yọ̀
Kí Yosí ma tá mi bí t'Àbólò
K'ọ́n fun wọn tó ní Tetulá
All I need is my own, oh
Ah, mi ò mọ̀ pé ojú ogun le, ń bá ti gbé bazooka
I saw some shege, àánú ṣáà ni mo ń rí gbà
So, Ẹlẹ́dàá mi, mo bẹ̀bẹ̀
Ibi t'ọ́n wa moto, kí n má lọ lo keke
I for don die, ọpẹ́lọpẹ́ mo rí jà
Àwa dé, dé, dé, dé, dé, dé, àwa dé
Àwa la ń gbé wọn dé'bẹ̀, àwa dé o, mm
Àwa dé, dé, dé, dé, dé, dé, àwa dé
Ṣebí àwa la ń gbé wọn dé'bẹ̀?
Àwa la ń gbé wọn dé'bẹ̀, àwa dé o
Ṣebí àwa la ń gbé wọn dé'bẹ̀?
Wähle Zeilen aus, um sie zu teilen. Du kannst bis zu 6 Zeilen auswählen. Mit den Pfeiltasten wechselst du zwischen Zeilen, die Leertaste wählt aus, Umschalt mit den Pfeiltasten wählt einen Bereich, Escape hebt die Auswahl auf.
